Ìjọba orílẹ̀-èdè Ethiopia ní òhun tí ya Àádọ̀rún mílíọ̀nù Dọ́là ṣọ́ tọ̀ láti fí bẹ̀rẹ okówó ilé ìfowópamọ́ sí ní Tigtayan
Ààrẹ Abiy’s àti olùmọ̀ràn fún ètò ààbò,Tedwan Hussein lo ṣe ìpolongo ọ̀rọ̀ yìí ninu ẹ̀rọ ayélujára Twitter,wí pé Ilé Ifowopamọ gbogbogbò tí bẹrẹ̀ sí ní fi owó ránṣẹ́ sí Olu ìlú náà ni Mekele fún pìpì re ní ọjọ́ Ajé.