Ìjàmbá iná tó ṣe yọ ni orílẹ̀-èdè Chile lo ti gbà ẹ̀mí àwọn ènìyàn mẹ́tàlá, tí ó sí bá àwọn ilé tó tó Márùndìnlógójì jẹ
Eleyi wáyé látàrí orun gbígbóná tó fẹ wa lati ìwọòrùn ilu náà
Mínísítà fún ọ̀rọ̀ ọ̀gbìn sàlàyé wí pé àwọn òṣìṣẹ́ pajawiri kàn náà bá isele naa lọ lakọkọ ti ọkọ ofurufu wọn Jabo lulẹ̀ látàrí ìjàmbá náà.
Mínísítà Carolina Tosha ni, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé to tó ọgorun lo ti bajẹ, ìjàmbá iná tó wáyé ní àrin okandinlelogoji láàrin orìlẹ́-èdè náà,
Ọ̀pọ̀ àwọn ẹbí lo n wáyé láti fori wọn pamó sì.