Take a fresh look at your lifestyle.

Inú Mi Kò Dun Bi Wọn Ṣe Pa Àwọn Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ní Orílẹ̀-èdè Burkina Faso.: Ààrẹ Buhari

0 118

Ìròyìn tí kò dùn mọ ni nínú lo tó ààrẹ Muhammadu Buhari létí nípa àwọn àrin rin àjọ lọ sí ilé Mecca tí àwọn ẹni ìbí se ku pá pẹ̀lú ìbọn.

Ààrẹ fi ẹ̀dùn inú rẹ hàn gidigidi lórí iku wọn,o sí gbàdúrà fún ààbò àwọn tòkùn tó sí wà lóhùn.

Mínísítà tó n sójú orílẹ́-èdè Nàìjíríà ni orílẹ́-èdè Burkina Faso,ni àwọn dúró láti gbọ ibà jáde ìwádìí lori ọ̀rọ̀ náà fún ìdájọ òdodo.

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà fí dá àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà loju wí pé ìjọba yóò ṣe ètò ààbò tó péye fún àwon àrin rin àjọ tòkùn.

Leave A Reply

Your email address will not be published.