Gómìnà ìpínlẹ̀ Katsina,Aminu Masari tí sàlàyé àwọn gbógì àǹfààní to n bẹ nínú ẹ̀kọ́ kíkà,ó ni ẹ̀kọ́ lọ jẹ́ kọ́kọ́rọ́ tó n ṣilẹkun fun àwọn asiwaju rere níbi iṣẹ́ gbogbo.
O ní kí gbogbo awọn olori wa ri wí pé ètò ẹ̀kọ́ kò parun ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Nínú ìpàdé pẹ̀lú àwọn oníròyìn ilé ìjọba ni ìpínlẹ̀ Katsina ni Gómìnà tí sọ èyí di mímọ̀, ó ní pẹ̀lú gbogbo ìdojúkọ tó wáyé nínú ìjọba òhun ètò ẹ̀kọ́ sí ṣe kókó julọ.
Nínú ọ̀rọ̀ Gómìnà, o ní fún a rí dájú wí pé òhun ṣiṣe takuntakun fún ìlọsíwájú ètò ẹ̀kọ́, wọn rí wí pé iyato nla bá àwọn ọmọ ilẹ ìwé Gírámà ni ìpínlẹ̀ náà.