Oǹkọrin omọ Naijiria ti gbé àwo orin tuntun jade to pe akole re ni – ‘Dúró timi‘. Eléyìí mú kí inú àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ dùn jọjọ síi.
Phillip Kayode Moses ni wọ́n bí ní ọjọ́ karún ún oṣù kẹfà ọdún 1994 ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ìnangije rẹ̀ ni Pheelz.
Ó ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ òṣèré àti Oǹkọrin bíi Ọlámídé ati Tiwa Savage. A bíi, a sì tún tọ́ọ ni ìlú Èkó. Pheelz se nínú àwo orin kan “Baddest Guy”ti gbajúgbajà Oǹkọrin tí a mọ̀ sí Ọlámídé.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san
Leave a Reply