Mọ̀kàn mọ̀kàn loyè ń kàn, Èmi ló kàn báyìí – McDonald ló sọ bẹ́ẹ̀ fún Nadal nínú ìdíje Australia
Aṣiwaju agbabọọlu oní ẹ́ẹ̀gì orílẹ̀-èdè Australia Rafael Nadal ti jade kuro nínú ìdíje oní ìpele kejì lẹ́hìn ti o farapa lákọ̀kọ́ọ́ ti o pàdánù ìpele oní mẹfa sí mẹrin sí mẹfa sí meje sí marun (6-4 6-4 7-5) nípasẹ̀ akẹgbẹ́ rẹẹ̀ tó jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè American Mackenzie McDonald.
Ṣaájú kí ó tó farapa McDonald ti ṣere ti o dara sẹyin láti yege nínú ìpele àkọ́kọ́, ní bi tí ó ti figagbága pẹ̀lú Spaniard ọmọ ọdún mẹrindinlogoji ti o si borí púpọ̀ nínú àwọn ìpele tí ó lágbára yìí
Nadal gbìyànjú láti fakàngbọ̀n pẹ̀lú McDonald sùgbọ́n kòsí ipá fún, lẹ́yìn tí ó tiraka láti dé ìpele kẹta ni McDonald wá paá sí àmì ayò mẹ́fà sí márùn-ún (6-5)
https://help.twitter.com/en/twitter-for-websites-ads-info-and-privacy
Ọláyinká G. Akíntọ́lá.