Take a fresh look at your lifestyle.

Lílo Ògún Lẹ́mẹ̀taa Lôjúmó Yóò Dẹkùn Ààrùn Ibà Ni Áfríkà.

0 148

Ìwádìí ti fi hàn wípé lílo ògún àrùn ibà nígbà mẹ́ta àti èyí tí ó ṣiṣe kíákíá áti èyí tó n ṣiṣe diẹdiẹ ni iwọ òòrun Áfíríkà yóò dẹkùn ààrùn ibà lára tọmọde tagba.

Ìwádìí yí wà láti ilẹ ẹkọ gíga Maryland Center For Vaccine.

Ìpàdé yìí ni àwon ènìyàn ọgọrin kopa ninu rẹ láti wá ìyanjú àlàáfíà sí ohun ilera pẹ̀lú imojuto oṣù Méjìdínlógún.

Ìwádìí sí nlọ lówó ní ilé ẹkọ gíga náà fún iyànjú àlàáfíà fún àwọn arìnrìn àjọ àti àwọn ajagun,esi ìwádìí ni wón retí kó jáde lọdun

Leave A Reply

Your email address will not be published.