Èdè tí wà ọ̀nà abayọ sí àlàáfíà àìsàn Kídìnrìn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà wọ́n tí rọ ìjọba àpapọ̀ àti àwọn àjọ míràn láti wá ònà abayọ sí àìsàn Kidinrin sí gbogbo agbaye.
Nínú ọ̀rọ̀ ààrẹ ẹgbẹ́ náà Oníṣègùn Òyìnbó Adanze Asinobi sọ wípé owó tí wọ́n ná lórí àìsàn náà pọ̀jù, fún ìdí èyí ki ìrànlọ́wọ́ dìde.
Ìpàdé ọlọjọ mẹ́rin to bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kẹwàá sí ọjọ́ kẹrinla oṣù kini ọdún 2023.
Leave a Reply