Take a fresh look at your lifestyle.

Ìpínlẹ̀ Edo Ṣe Ìrànlọ́wọ́ Fún Àwọn Àgbẹ̀ Ọlọ́sìn Adìẹ

0 178

 

Ìjọba ìpínlẹ̀ Edo, pẹ̀lú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn ilé iṣẹ́ ọlọ́sìn Adìẹ yóò se ìrànlọ́wọ́ fún àwọn àgbẹ̀ ẹgbẹ̀rún lọ́nà ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (500,000).

 

Ó fi ọ̀rọ̀ náà léde níbi àpéjọ kan ní Ikpoba, ìjọba ìbílẹ̀ Okha. Gẹ́gẹ́ bí ó se sọ, ìpínlẹ̀ náà ti setán láti ran àwọn àgbẹ̀ ọ̀sìn adìẹ lọ́wọ́ ní ìpínlẹ̀ Edo, lójúnà àti mú ìgbòòrò bá ọrọ̀ ajé àti ìgbáyégbádùn.

 

Ó sàlàyé síwájú pé, ìgbésẹ̀ náà yóò pèsè iṣẹ́ fún ọ̀pọ̀ ènìyàn.

Leave A Reply

Your email address will not be published.