Ni igbaradi fún eré ìdíje lorisirisi ọ̀nà lórí papa ti Paris 2024, àjọ àgbáyé ilé áfíríkà ti fọwọ́ sí kí orílẹ̀-èdè Tunisia gbàlejò àwọn orílẹ̀-èdè láti figagbága fún ìdíje náà .
Orílè-èdè Tunisia yóò gbelejo idije ẹlékẹ́tàlá irú rẹ, ni èyí tí yóò mú àwọn kópa lọ́dún ti bọ nínú ìdíje Paris 2024.
Orílẹ-èdè Tunisia jẹ́ Orílẹ-èdè tọ Kàjú òsuọ́wn láti gbàlejò náà