Ààrẹ Muhammadu Buhari tí yan Ọgbẹni Osita Anthony Abolama gẹ́gẹ́ bí alága tuntun fún ìgbìmò ohun tó níye lórí.
Nínú àtẹ̀ jáde kan láti ọwọ́ Mínísítà fún káràkátà, Ifedayo Sayo, ó ní ipò tuntun náà tó iṣẹ rẹ bẹrẹ lati oṣù kẹjọ o 2022 jẹ́ àtúnyàn sípò gẹ́gẹ́ bí elekeji gégé bí alága fún ẹgbẹ́ nàá