Edson Arantes do Nascimento tí gbogbo ènìyàn mọ sí Pele ti di oloogbe, Pele nikan ni agbabọọlu ninu ìtàn láti gba ife idije Agbaye lẹmẹta.
Abí oloogbe ni ọjọ kẹtalelogun osu kẹwa, ọdun 1940 sí Três Corações, State of Minas Gerais, Brazil
O ku sí ile-iwosan Albert Einstein ni Sao Paulo lẹhin to jija du emi rẹ pẹlu aisan Káánsà (Cancer); o di ẹni ti aye ń fẹ lẹyin ti o gba Ife Agbaye ni ọdun 1958 ní ọmọ ọdun mẹtadinlogun, o gba bọọlu wọ inu àwọ̀n lẹẹmeji ní bi idije asekagba lati ṣẹgun orilẹ-ede Sweden ti o gbalejo rẹ
Ọláyinká Akíntọ́lá.