Take a fresh look at your lifestyle.

Àjọ Kan Pè Fún Kíkorò Ojú Sí Fífi Ọmọ Sòwò Ẹrú

0 114

Ọ̀gá àgbà àjọ tí ó ń gbógun ti fífi ọmọ sòwò ẹrú, Task Force For Human Ttafficking, ti ìṕinlẹ̀ Anambra, ọ̀jọ̀gbọ́n Sylvia Chika Ifejeme sọ wípé àwọn ẹ̀ṣọ́ àjọ náà gbọdọ̀ gbáradì fún ojúse tí ó péye.

 

Ó fi ọ̀rọ̀ náà léde níbi àpérò pàtàkì tí ó wáyé ní Jerome Udoji, ní ìlú Awka.

 

Ọ̀jọ̀gbọ́n Ifemeje tún sọ wípé wọn yóò fi àwọn alákòsóo pàtàkì lọ́lẹ̀ fún àjọ náà ní ọdún 2023 tí yóò máa mójú tó isẹ́ rẹ̀ fún àseyọrí rere. Ó sì jẹ́jẹẹ́ àtìlẹyìn àti ojúse tí ó péye fún àjọ náà.

Leave A Reply

Your email address will not be published.