Take a fresh look at your lifestyle.

àdo olóró pa ènìyàn mẹ́ta ní ìpínlẹ̀ Kogi lásìkò tí ààrẹ Buhari ṣe àbẹ̀wo

0 197

àdó olóró ni ó bú gbàmù  ni ilu  Okene, ti ko jinna si aafin ọba Ohinoyi to wa ni agbegbe  Kuroko ní Okene.to  jẹ ẹkun ìpínlẹ̀  Kogi nibi ti gomina ipinlẹ naa,  Yahaya Bello ti wá.

O ku wakati diẹ ti aarẹ Buhari  yoo ṣe abẹwo si awọn isẹ akanse pataki ti gomina Yahaya Bello se ni ipinlẹ Kogi ọhun, ni isẹlẹ àdó olóró  naa waye lonii.

awọn ahesọ to n waye ni pe ikọ̀ ọlọ̀tẹ̀ lo se ijamba ọhun , ti awọn kan si n sọ pe ẹ̀rọ amúnáwá  iyẹn  transformer  lo fa isẹlẹ ọhun.

ni bayii, iroyin sọ pe awọn eniyan mẹta lo ti padanu ẹ̀mí wọn, , nigba ti awọn kan ṣi farapa yẹ́lẹ-yẹ̀lẹ nibi isẹlẹ ọhun..

 

ìròyìn lẹ́kùnún rẹ́rẹ́ ń bọ̀….

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button