Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti ṣètò Ìgbìmọ̀ Tó Ń Bójú Tó Àjálù Omí yalé

0 171

Ìjọba orilẹ-ede Nàìjíríà ti ṣeto Igbimọ Alakoso fún Ìdàgbàsókè ètò Iṣẹ fún Ìdènà àwọn àjálù omí yalé ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Nígbàtí wọn ṣe ìfilọ́lẹ̀ ìgbimọ náà ní ìlú Abuja, olú-ìlú orílẹ̀-ède Nàìjíríà, Mínísítà fún ọ̀rọ̀ Omi, Suleiman Adamu sọ fún àwọn igbimọ náà láti ṣe àgbékalẹ̀ àwọn ojútùú láti dènà àwọn àjálù Omí yalé ọjọ́ iwájú

Gẹgẹ bí Mínísítà náà, kìí ṣe ìròyìn mọ́ pé omí yalé ọdún 2022 yìí ti sọ ọpọlọpọ àwọn agbègbè sínú ìnira, àwọn ilé ti o wa ni inú omi àti àwọn dukia tótó biliọnu naira ló ti bàjẹ́ sí nú ẹ̀

ỌLÁYINKÁ AKÍNTỌ́LÁ

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button