Take a fresh look at your lifestyle.

CAF Tún Ṣí Ayé Sílẹ̀ Fún Ìgbálejo AFCON 2025

1 301

Àjọ Bọ́ọ̀lù Afẹsẹgba Ilẹ̀ Áfíríkà tí CAF tún ṣí ìlànà ìfilọ́lẹ̀ fún ẹtọ́ gbigbàlejò TotalEnergies Africa Cup of Nations (AFCON) 2025

CAF fí àkíyèsí yìí ránṣẹ́ sí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ láti ṣé àfihàn ìfẹ́ wọ́n sí gbigbàlejò AFCON 2025 pẹ̀lú ìlànà tí yóò tẹlé ní yíyan orílẹ-èdè tàbí àwọn orílẹ̀-èdè tó fẹ gbàlejò.

AFCON 2025: Ìlànà ìkópa nínú ìgbálejo

➡️ Ọjọ́ kọkànlá Oṣù kọkànlá 2022: Àkókò ìparí gbígbà fọọmu ìkópa sílẹ̀
➡️ Ọjọ́ Kerindinlogun Oṣù kọkànlá 2022: Àkókò lati fí lédè gbogbo orílẹ̀-èdè tó fí ìfẹ hàn láti gbàlejò
➡️ Ọjó Kerindinlogun Oṣu Kejìlá ní, Àkókò ìparí láti dá àwọn fọọmu padà fún Àjọ CAF
➡️ Ọjọ́ Karún sí ọjọ́ karundinlọgbọn Oṣu Kini Ọdun 2023: Àwọn àbẹwò káàkiri
➡️ Ọjọ́ kẹwàá oṣù Kejì 2023: Ifi lédè Orílẹ̀-èdè/Àwọn orílẹ̀-èdè tó peregede láti gbàlejò láti ẹnu àwọn Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ CAF.

Lekan orenuga

1 Comment
  1. […] Tún kà nípa:CAF Tún Ṣí Ayé Sílẹ̀ Fún Ìgbálejo AFCON 2025 […]

Leave A Reply

Your email address will not be published.