Take a fresh look at your lifestyle.

Indian 2022: Ẹgbẹ́ agbábọ̀ọ̀lù Obìnrin Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (U-17) gbìyànjú ṣùgbọ́n omí pọ̀ ju ọkà lọ nínú ìdíje eré bọ́ọ̀lù pẹlu Ẹgbẹ́ agbábọ̀ọ̀lù Colombia

0 100

Ẹgbẹ́ agbabọọlu Obirin U-17 ti Naijiria, Flamingos, ti já kúrò nínú ìdíje FIFA U-17 ife àgbáyé, ọdún 2022 nipasẹ fífi ìdí rẹ mi nínú eré bọọlu pẹlu awọn agbábọ̀ọ̀lù Colombia wọn gbìyànjú diẹ ṣugbọn ìgbìyànjú wọn kò tó, won jẹ àmì ayo mẹfa sí marun (6-5) ni pẹnátì lẹyin amiy ayo 0-0 ni eré akoko, ni papa iṣere Pandit Jawaharlal Nehru ni Margao, India.

Àwọn Flamingos bẹrẹ pẹlu ìgbìyànjú to da músé ṣugbọn wọ́n kùnà láti yẹ golí Colombian wò. Eré ní ìdádúró ni iṣẹju mejidinlogun lẹhin ìjà láàrin Edidiong Etim àti Mary Espitaleta.

Awọn Obirin U-17 ti Ilu Columbia kú oríire lẹhin ti wọn ní iṣẹgun níbi ìpàdé nlá ṣùgbọ́n tí ọ jẹ́ Ìbànújẹ fun awọn ọmọ Nàìjíríà láti jáde báyìí ṣugbọn kini irin-ajo.

Nàìjíríà yóò máa gbá bọ́ọ̀lù pẹlu agbábọ́ọ̀lù Spain tàbí Germany fún ipò kẹta nínú ìdíje FIFA U-17 ife àgbáyé, ọdún 2022 ní ọjọ́bọ.

Leave A Reply

Your email address will not be published.