Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Tí Ìjàmbá Omí Yalé Ṣẹlẹ̀ sí Gbà Ẹ̀bùn Ìṣura Ní Ìpínlẹ̀ Niger.

0 98

Àjọ tó mójú tó ọ̀rọ̀ pàjáwìrì ní ìpínlẹ̀ Niger, tí sí jú àánú wo àwọn tí ìjàmbá omí yalé ṣẹlẹ̀ sí nípa fífún wọn ní oríṣiríṣi ẹbùn ìṣura.

Olùdarí àjọ fún òrò pàjáwìrì ní ìpínlẹ̀ Niger,Ahmed Ibrahim Inga, ti bẹ̀rẹ̀ pínpín àwọn èròjá ẹbùn náà ni ìjọba ìbílè kuchiworo, lára àwọn agbègbè tí Ìjàmbá ṣẹlẹ̀ sí.

Nigba ti o bá àwọn tọ́rọ̀ náà kàn kẹ́dùn,o ni kan fí ọkàn balẹ pé ìrànlọ́wọ́ mbè fún wọn, láti ọwọ́ ìjọba àti àjọ tó mójú tó ọ̀rọ̀ pàjáwìrì.

Leave A Reply

Your email address will not be published.