Take a fresh look at your lifestyle.

O Ṣeéṣe Kí Isak Má Kópa Nínú Ife-Àgbáyé

0 134

Agbàbọ́ọ̀lù Newcastle United Alexander Isak ló ṣeéṣe kó má kópa nínú ìfe-Àgbáyé tí yóò wáyé ní oṣù kẹsán latari ifarapa tó ní nígbàtí o ń ṣoju Orílẹ̀-èdè rẹ̀, Sweden, Àkọnímọ́ọ̀gbá Eddie Howe.

Isak, ọmọ ọdún mẹ́tàlélogun (23), tí kópa nínú ifẹsẹwọnsẹ mẹ́ta fún ìkọ̀ Newcastle Láti ìgbá tó tí darapọ̀ mọ́ wọ́n láti Real Sociedad ní òye owó £60m ní oṣù kẹjọ tó sí gbà ayò wọlé nínú ifẹsẹwọnsẹ pẹlú Liverpool.

“Howe ṣàfikún ọrọ rẹ̀ ṣáájú ìdíjé Premier League tí Ọjọ́bọ̀ ní ilé Everton (19:30 BST), o ṣeni láànú púpọ fún bí àgbàbọ́ọ̀lù tuntun ní lìígì tuntun náà ṣé ní ifarapa.

Ìfe-Àgbáyé ní yóò bẹ̀rẹ̀ ní ògún-jọ́, Oṣù kọkànlá, ọdún 2022 ní Qatar.

Lekan orenuga

Leave A Reply

Your email address will not be published.