Take a fresh look at your lifestyle.

CAF CC: RS Berkane na Kwara United jáde nínú ìdíje

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 354

RS Berkane orílẹ̀-èdè Morocco gbá Aṣojú Nàìjíríà nínúu ìdíje àkójọpọ̀ ife ẹ̀yẹ agbábọ́ọ́lù Adúláwọ̀ ,CAF, Kwara United  jáde kúrò nínú ìdíje náà.

RS Berkane opened the scoring through Cheick Quattara on 17 minutes.

Afonja worriors ja fitafita sugbọn wọn papa padanu eeji si ookan lẹyin ti North African Side sọ ọkọọkan sile rẹ ninu abala mejeeji.

Ni ipari idije ,abajade jẹ eeji si eeji sugbọn Afonja worriors padanu.

Ilorin Club ti kọkọ ni aṣeyọrii ẹẹta si ookan ni ilu Eko, ni ipari ose ni ilodi si ẹgbẹ kanna.

Rs Berkae kọkọ sọ bọọlu si ile Cheick Qutratara laarin iṣẹju mẹtadin-logun.

Leave A Reply

Your email address will not be published.