Take a fresh look at your lifestyle.

UNGA, Ẹ̀tàdínlọ́gọ́rin: Ààrẹ Buhari Padà Sí Ìlú Abuja.

0 69

Ààrẹ Muhammadu Buhari ti padà sí ìlú Abuja lẹhin ti o kópa nínú ìpàdé, àjọ àgbáyé ti Ẹ̀tàdínlọ́gọ́rin.

Ààrẹ balẹ́ ní òwúrò kùtù sí pápá ọkọ̀ òfurufú ti Nnamdi Azikiwe ti o wa ni ìlú Abuja, ni ọjọ Ajé.

Koko ìpàdé náà ni wipe, Ààrẹ ni pé ká ní ìdánilójú wí pé àlàáfíà yóò jọba nínú ìdìbò ọdún tí nbọ.

O ṣe ìpàdé pẹlú àwọn alágbàṣe pẹlu orílẹ̀-èdè Nàìjíríà káàkiri àgbáyé, níbi tí o ti fi dá wọn lójú wípé idojukọ lori ètò àbò yóò to di ohun ìtàn.

O tẹ̀síwájú nígbàtí ti o pé àwọn adarí Áfíríkà lati gbé ìwà ìbàjẹ́ tí.

Leave A Reply

Your email address will not be published.