Take a fresh look at your lifestyle.

Mínísítà Gbà Àmì Ẹ̀yẹ Olú tọju Awọn Eniyan Ti Áfíríkà.

0 83

Mínísítà fún ìtọ́jú àwọn ènìyàn àti agbègbè,Sadiya Umar Farouq,ni àwọn adarí obínrin Áfíríkà gbe àmín ẹyẹ tuntun lẹ lówó.

Àmì ẹyẹ àti idanilola náà ti, onírúurú awọn oni ṣòwò ni òkè òkun gbà láti dá Umar Farouq lọ́lá ni orílẹ-èdè United kingdom.

Nínú ìdúpé rẹ lẹ́hin gbígba àmì ẹ̀yẹ náà Umar Farouq dúpẹ́ gidigidi lọwọ àwọn alákòóso ètò náà

Leave A Reply

Your email address will not be published.