Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjí Líle Pa Ènìyàn Márùún Ní orílẹ̀-èdè Filipi.

0 98

Ìjí Líle typhoon Noru,ti o kọ lù àwọn ilé agbègbè Filipi,ti pa oṣiṣẹ elẹ́tó àbò márùn.

Gómìnà ìpínlẹ̀ Bulacan, Daniel Fernando,sọ wípé àwon elẹ́tò àbò márùn,lo ṣe ìjàmbá omí yalé náà , nígbà tí wọn ṣe iṣẹ́ wọn ní San Miguel .

Ogbeni Marcos ti pàṣẹ láti pé ṣe gbogbo ohun to ni lọ fún àwọn tó jàmbá náà ko lù ni agbegbe naa.

Leave A Reply

Your email address will not be published.