Take a fresh look at your lifestyle.

Comic-Con Áfíríkà Padà Lẹ́yìn Ajakalẹ-Àrùn

0 124
Àìmọye àwọn Olólùfẹ́, Ọtayo ati Olùkópa ní wọ́n kópa nínú Akọkọ Ìdíje Ere Comic Con Áfíríkà lẹ́yìn Ajakalẹ-Àrùn ti ó wáyé jákèjádò Àgbàye.”

 

Àpéjọ Ọlọ́jọ́ mẹ́rin wáyé láàárín ọjọ́ Kejìlélógún sí ikẹdọ́gbọ́n Oṣù Kẹ̀sán, ohùn ní ó tóbi jùlọ nínú Àjọ̀dún Èré Ibílẹ ati Ayo títà ni ilẹ̀ Adúláwọ.  Àwọn míràn wá ní bẹ fún Ìgbàdùn, nígbà tí àwọn míràn ń sọ̀rọ̀ nípa, Johannesburg-based Thifhuriwi Nephawe.
Ó múra bí Ọmọbabinrin Neytiri Àjèjì ti ìdíje Na’vi, nínú Èré Amẹ́ríkà ti Avatar.

 

Akopa Neytiri wa fún mi, gẹ́gẹ́ bíi Obìnrin Áfíríkà tí ó lágbára gidigidi tí ó ń jà fún abúlé ati ẹ̀yà rẹ,” arábìnrin yí sàlàyé.”
Àwọn Ará ìta ń gbìyànjú láti gbà gbogbo ohùn tí wọn ní lọ́wọ́ wọ́n, nítorí náà ó n jà fitafita láti má jẹ kó rí bẹ, ó hùn-ùn ti mo dúró fún nìyí gẹ́gẹ́ bí Alágbára.  Kí a sì mọ wí pé Akíkanjú ati Alágbára ní a jẹ gẹgẹ bí Obìnrin Adúláwọ ní tí tèmi gẹgẹ bí ẹnìkàn.”

 

Àwọn ohùn ìṣeré oriṣiriṣi ati Àwọn ìkójọpọ wa pẹlu Àwọn ènìyàn tí ó wà nínú àwọn Ọgbun supahiro, awọn iboju iparada, awọn aṣọ sci-fi ati awọn wigi ẹsẹntiriki ni ile-iṣẹ iṣafihan nitosi papa isere FNB, eyiti o gbalejo ipari idije Ife Àgbàye FIFA 2010.

 

Luke Andalis tí ń kópa ninu Èré cos fún ọdún mẹ́fà, ó ní àwọn tí wọ́n ń ṣe aṣọ àwọn Òṣeré ti ohùn tí ṣé fún ọdún méjìlá ní ó fún ohùn ní àǹfààní láti sípò padà si Ìdíje yí.

 

Olubunmi Adeyẹmọ.
Leave A Reply

Your email address will not be published.