Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Ti Ọrọ Kan, Dẹkùn ìwà ìbàjẹ́ Lórí Obínrin:Ìpínlè Gombe: 

0 81

Ìjọba ìpínlè Gombe,to n mójú tó ọ̀rọ̀ ará ìlú, ti ṣe àtìléyìn fún àwọn tọrọ kan, pápá jùlọ àwọn tí wọn bọ lọwọ ìṣòro ìwà ìbàjẹ́, lati fohumo, láti fẹjọ́ sun ati láti dẹkùn ìwà ìbàjẹ́ ní ìpínlè náà.

Awọn akópa náà je ọdọ’mọbirin kẹkẹre,àgbàlagbà obìnrin, àwọn Ọba àti àwọn olórí ìlú, àwọn olórí èsìn pẹlu àwọn èsọ́ aláàbò.

 

Awọn ọdọmọbìnrin náà fi ẹdun inú wọn hàn, lórí ohun tí wọn ti kojú ni ìpínlè Gombe,awọn bíi ìgbéyàwó ti kò tọ,ifi ipá bani lọpọ, ìlò ọmọ ni ìlò ìká.Won tẹ̀síwájú pé didán ọmọ Obìnrin mọ nínú ẹbí and pàtàkì ẹ̀kọ́ fún wọn, àti láti pá àwọn òfin kánkan rè kí ijiya lẹ wá fún mí ẹni tó bá fi ipá bá obìnrin lọpọ, àti ki àwọn òbí fún ọmọ Obìnrin ni akọkọ àti a yẹ larin ẹgbẹ.

Leave A Reply

Your email address will not be published.