Take a fresh look at your lifestyle.

Ogun Ukiréìnì:Rọ́síà ti ogunlọ́gọ̀ ènìyàn mọ́lé fún ìfẹ̀hónúhàn

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 100

Ó ju ọgbọ̀nlé-lẹ́ẹ̀dẹ́gbẹ̀rin ènìyàn lọ tí wọ́n tì mọ́lé jákèjádò orílẹ̀-èdè Rọ́síà lórí bí wọ́n ṣe ń fi ẹ̀hónúhàn láti lòdì sí àṣẹ àkójọ ní ọjọ́ Àbámẹ́ta, ẹgbẹ́ ẹ̀tọ̀ kán sọ.

Atimọle naa waye lẹyin  ọjọ mẹta ti Aarẹ Vladimir Putin paṣẹ fun awọn ologun Rọsia akọkọ  lati bọ sita fun Ogun Agbaye Keji fun rogbodiyan ni Ukireini.

Ẹgbẹ olominira alabojuto  OVD-Info  sọ pe oun mọ nipa awọn atimọle naa ni awọn ilu oriṣiriṣi mejile-lọgbọn, lati Sẹnti Petersburgi si Siberia.

Awọn apejọ ti ko ni aṣẹ jẹ irufin labẹ ofin orilẹ-ede Rọsia, ti o si tun lodi si igbesẹ eyikeyi  lati ba awọn ologun jẹ.

Leave A Reply

Your email address will not be published.