Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ̀tàdílọ́gọ́rin UNGA: Àwọn Adarí orílẹ́-èdè Nàìjíríà Sòrò Ìdágbére.

0 40

Ààrẹ Muhammed Buhari ti pinnu láti rí wípé ètò ìdìbò orílẹ̀-èdè Nàìjíríà yóò ni àlàfíà, ìrònú,ati ìwúrí nínú,ni eyi ti àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà yóò yan adarí ti wọn ba fè.

 

Nínú òrò ìdágbére rẹ sí àjọ ìrẹ́pọ̀ àgbáyé nínú ìpàdé gbogbogbòò tí lọ lọ́wọ́.Ó fí dì rẹ múlẹ̀ wípé lọdun tó nbọ̀ aṣojú tuntun ní yóò sọ jù orílẹ-èdè Nàìjíríà .

Nínú òrò ìparí rẹ,ààrẹ rọ gbogbo àwọn adarí lati gbé, òfin àlàfíà, ọ̀wọ́, àti ìwà ọmọlúàbí láàrín a ra wọn.

Leave A Reply

Your email address will not be published.