Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé Ẹjọ́ Òṣìṣẹ́ Pàṣẹ Kí Fásítì Dáwọ Ìyànsẹ́lódí Dúró.

0 34

Ilé Ẹjọ́ Òṣìṣẹ́ tí orilẹ́-èdè ni ìlú Abuja, tí pàṣẹ wípé kí ẹgbẹ́ àwọn olùkọ tí Fásítì orílẹ̀-èdè Nàìjíríà dáwọ́ ìyànsẹ́lódí tó nlọ lọ́wọ́ láti oṣù keje sẹyìn.

 

Mínísítà fún àwọn òṣìṣẹ́ and gbigba ni siṣẹ , Onísègùn Chris Ngige,ti sojú ìjọba Nàìjíríà, tí pẹ ejò láti wá ìyanú sí ọrọ Ìyànsẹ́lódí to nlọ lọwọ pẹlú ẹgbẹ́ ASUU.

Leave A Reply

Your email address will not be published.