Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin ti bẹ̀rẹ̀ Ìwádìí nípa Àgùnbánirọ̀ tí ọmọ orílẹ̀-èdè Chinese dá ẹ̀mí rẹẹ̀ légbodò.

0 38

Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àpapọ̀ ti pàṣẹ ìwádìí lati tọ pínpín ikú tí o pá àgùnbánirọ̀ tí o pàdánù èmi rẹ ni ìpínlè Kano.

Ará bìnrin náà èyí tó njẹ omidan Ummulkulthum Buhani pàdánù èmi rẹ nínú ilé rẹ Janbulo, Dorayi Babba ni ìbílè Gwale ti ìjọba kano.

Olóògbé náà ní èmi rẹ jábó láti ọwọ, ògbéni Geng Quanrog, tó wá láti ìlú Chinese,ni dédé agọ mésàn àbò alé.

Àṣẹ yìí wáyé ọrọ ipe pajawiri lórí ohun tí nlọ l’arin ìlú àti kókó pàtàkì láti wádií.Ọnarebu Kabiru Alhassan Rirum pàṣẹ láti dáwọ́ iṣẹ dúró ní ilẹ̀ iṣẹ awọn Chinese náà, titi dì gba ti ìdájọ́ yóò wáyé.

Leave A Reply

Your email address will not be published.