Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Buhari Yan Dembos Gẹ́gẹ́ Bí Olùdarí Àgbà Ìlé-íṣẹ́ NTA

0 44

Ààrẹ Muhammadu Buhari tí yan ọ̀gbẹ́ni Salihu Abdulhamid Dembos gẹ́gẹ́ bí Olùdarí Gbogbogbò/Adari Àgbà tí iṣẹ́ tẹlifíṣọ̀n Nàìjíríà (NTA).

Mínísítà fún ètò ìròyìn àti àṣà, Alhaji Lai Mohammed, ló kede iyansipo náà nínú àtẹ̀jáde kàn ní Abùjá Olú ìlú orílẹ-èdè yíì ní Ọjọ́rú.

“Iyansipo náà jẹ́ èyí tí yóò ṣe ní ọdún mẹ́ta ní ìbẹrẹ ìṣàkóso náà.”

Ọgbẹni Dembos lo tí jẹ́ Alákóso Àgbà ní ẹka itaja, NTA tẹlẹ rí.
O tún tí ṣiṣẹ́ gẹgẹ bí Alákóso Gbogbogbò tí àwọn Ibusọ NTA méjì ní Lokoja ati Kano; ati bí Olùdarí àgbègbè (Zonal Director), NTA, Kaduna láàrin ogún ọdún rẹ ni ilé-iṣẹ́ náà.

Lekan orenuga

Leave A Reply

Your email address will not be published.