Take a fresh look at your lifestyle.

Ariwoola di Adájọ́ Àgbà Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà – Àwọn ìgbìmọ̀ aṣòfin.

0 37

Àwọn aṣòfin àgbà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí fi owó fi sí Adájọ Àgbà Olukayode Ariwoola gégé bí adájọ àgbà fún orílẹ-èdè Nàìjíríà.

Èyí wáyé lẹhin ìfọ̀rọ̀wéró pẹ̀lú rẹ ní ìlú Abuja lójórú, ọjọ́ kánkànlẹ́lógún ọdún yìí.
Ariwoola nínú òrò ìdáhùn rẹ, kọ tó gbà wọlé,oni òpó idojukọ to wáyé láàrin ilé ẹjọ ni wípé a yí wà ìdí òrò ni kikun.

O rọ àwọn ìgbìmò ásòfin lati,ma bú ọ tẹ lù àwọn owó tó ni ṣe pẹlú àwọn adájọ, láti lè jẹ kí wọn ṣiṣẹ wọn dáradára.

Leave A Reply

Your email address will not be published.