Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Eléré Ìdárayá Àgbáyé Fí Orúkọ Tobi Amusan Sí Ìwé Ìtàn

0 63

Àwọn alákòóso èré ìdárayá ní àgbáyé tí fi orúkọ Tobi Amusan ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí o n sáré fogi-fogi ìyẹn ti 100m hurdles sí ìwé ìtàn àgbáyé ni 2022.
Nínú àlàyé kàn ní ọjọ Ìṣẹgun, ẹgbẹ́ eléré Ìdárayá náà tún fọwọ́sí àwọn méjì míràn tíì ṣé, Mondo Duplantis ati Sydney McLaughlin.

Gbogbo àwọn ifakọyọ wọ́n tí o wáyé ní bí eré-ìdárayá Àgbáyé tó wáyé ní Oregon, Amẹ́ríkà ní Oṣù Keje.

“Àwọn eleto ìgbà orúkọ sílẹ̀ àgbáyé ti a ṣeto nipasẹ bí Tobi Amusan, Mondo Duplantis ati Sydney McLaughlin ni bí awọn èré ìdíje ti wọn ṣe níbí èré ìdárayá gbáyé Oregon22 tí jẹ́ ifọwọsi.

Amusan lo sa èré fogi-fogi to sí parí ni àkókò tó kéré jùlọ lágbayé ìyẹn ní 12.12mins. Duplantis ni tirẹ̀ parí ní àkókò perete 6.21m, ti McLaughlin náà fí akọyọ ni iṣẹju 50.68 ní bí tó ti sáré fogi-fogi oni 400m.

Amusan ọmọ ọdún mẹẹdọgbọn ní ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àkọkọ tí yóò gbà àmì Wúrà wa lè. To sí tún gbà ti ilẹ Adúláwọ̀ àti Commonwealth òun lẹni akọkọ ti yóò ṣe irú rẹ̀.

Láìpẹ́ yìí ní orílẹ̀-èdè yìí bu ọla fún un, bí wọ́n ṣe fún ni Officer of the Order of the Niger, OON nípasẹ Ààrẹ Muhammadu Buhari.

Lekan Orenuga

Leave A Reply

Your email address will not be published.