Take a fresh look at your lifestyle.

Igbákejì Ààrẹ Ní Ọbabìnrin Elizabeth II Gùn Orí Àpèré Fún Ọdún Gbọ́ọ́rọ

0 131
Igbákejì Ààrẹ Orílẹ-èdè Nàìjíríà, Ọjọgbọ́n Yẹmi Ọṣinbajo ní Oloogbe Ọbabìnrin Elizabeth II gùn Orí Àpérè fún Ọdún gbọ́ọ́rọ, èyí tí ó mú ọgọrọ Ènìyàn wà péjọ pọ jákèjádò Àgbàye.  Ọ̀rọ̀ yìí wáyé níbí imọyi Olóògbé ni Òrùlé Lancaster ní Ọjọ́ Àìkú, ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹsàn-án, 2022.  O tún lo àǹfààní yìí láti darapọ mọ ìtó Lọwọọwọ ní òní kàn náà.

 

Nínú Ìwé Ìkẹdùn tí Igbákejì Ààrẹ kọ, ó jẹ kò dì mímọ pé “Nàìjíríà Darapọ mọ ìjọba Uk àti gbogbo àgbáyé láti kẹ́dùn pẹlu awọn ẹbí Ọbabìnrin tí ó wàja.  Kìí Ọlọ́run tẹ sì afẹ́fẹ́ rere.”
Ìpàdé wáyé láàrin Ọjọ́gbọ̀n Ọṣinbajo àti Akọwe Òkèèrè UK ní pàtó lórí ìdàgbàsókè àti ìgbèru Ọrọ-aje Orílẹ-èdè méjèèjì pẹlu èéto ààbò ní Gbùngbùn Ilẹ Adúláwọ.

 

Akọwe fú ilẹ̀ Òkèèrè UK kí Nàìjíríà kaabọ síbi ìsìnkú Ọbabìnrin tí ó wàjá, O fi imọyi hàn gẹ́gẹ́ bí Ọrẹ àti Olúbání kẹ́dùn nígbà tí wọn ńṣe Ọfọ Ọbabìnrin wọ́n.

 

Ní ìrọlẹ ọjọ́ Àìkú Ọba Charles III ṣe ìgbàlèjó Igbákejì Ààrẹ àti Olórí lágbáye ní Ààfin Buckingham.

 

Ní Ọjọ́ Ajé ni  Igbákejì Ààrẹ yòò máa kópa níbí ìsìnkú Ọbabìnrin ní Westminster Abbey.
Leave A Reply

Your email address will not be published.