Take a fresh look at your lifestyle.

Ewu Ńlá Wà Nínú Síse Ìtọ́jú Fún Ara Ẹni

0 99

Ìkìlọ̀ ti wáyé fún  ọmọ Nàìjíríà láti jìnà sí síse ìtọ́jú fún ara ẹni , eléyìí léwu fún ìlera.

 

Mínísítà ètò ìlera , Dókítà Osagie Ihanire fi ọ̀rọ̀ náà léde níbi ayẹyẹ ìrántí ọjọ́ ààbò ara ẹni ní ọjọ́ àìkú ní ìlú Àbújá.

 

Ó sọ pé, ìtọ́jú ara ẹni láì lọ sí ilé ìwòsàn tàbí ọ̀dọ̀ akọ́sẹ́ mọsẹ́ léwu jọjọ ju àìsàn ara gan-an lọ. Mínísítà lo ànfààní náà láti jẹ́ kí àwọn ènìyàn mọ ewu tí ó wà nínú síse ìtọ́jú fún ara ẹni àtipé kí àwọn ènìyàn jáwọ́ kúrò nínú mí máa se bẹ́ẹ̀ fún ànfààní ara wọn.

Leave A Reply

Your email address will not be published.