Take a fresh look at your lifestyle.

Àjọ Elétò Ìlera Pèpè Fún Ìtójú Tí Ó Péye Fún Àwọn Ọmọdé

0 78

Wọ́n ti rọ àwọn òbí láti máa fún àwọn ọmọ titun ní ìtọju tí ó péye, àtipé wọ́n gbọdọ̀ máa fún wọn ní ouńjẹ, ó kéré jù ní ẹ̀ẹ̀mẹfà lójúmọ́.

 

Amòye náà sàlàyé pé, àì fún àwọn ọmọ titun ní ìtọ́jú tí ó dára le è fa àìlera tí ó sì léwu fún ọjọ́ iwájú wọn.

 

Dókítà Renner náà tún se àfikún wípé, ọ̀sẹ̀ méjì àkọ́kọ́, òbí gbọdọ̀ máa fún ọmọ ní ọyàn ní wákàtí mẹ́rin-mẹ́rin sí ara wọn láti le è dènà àrùn àti fún àlàáfíà tí ó péye.

Leave A Reply

Your email address will not be published.