Take a fresh look at your lifestyle.

Oǹkọrin orilẹ èdè Nàìjíríà, Yemi Alade Gbé Àwo orin Tuntun Kan Jáde

0 84

 


Gbajúmò Olórin Afrobeats Nàìjíríà kan, Yemi Alade ti kọ orin tó gbé àdídùn Jamaican Dancehall artist Jáde nínú àwo orin tó pè ní ‘Bubble It’.

Orin náà  tí ó dín díẹ̀ ní ìṣẹ́jú mẹ́ta ló jáde ní ọjó kẹrìndínlógún oṣù kẹsàn án ọdún yìí, ni wọ́n tẹ̀, tí wọ́n ṣì tún gbé jáde láti ọwó Victor Kpoudosu labẹ̀ Effigy music group.

Yẹmi Àlàdé jẹ́ olùkọrin Afropop, ó ń kọ orin sílẹ, ó tún jẹ́ òṣèré àti olùkópa. Ó sí borí ìdíje ti Peak Talent Show ni ọdún, 2009.


Àwọn ènìyàn féràn àkòrí orin rẹ̀ tí ó pè ní
“Johnny” ní ọdún 2014 tí wọ́n fẹ́ láti gbọ́ àti jó sí. Eléyìí tó ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣe yìí tún leè dàbí rẹ̀.

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.