Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé Ìwòsàn Babcock Ṣé Ìṣẹ Àbẹ Ọkàn Fún ÓÒ Kéré Tán Ẹẹdẹgbẹ̀rún Lè Lọ́kàn Dín Lọ́gọ́ta Ènìyàn

0 107
Olórí Fásiti Babcock, Iliṣán Rẹmọ, Ọjọgbọ́n Ademọlà Tayọ, jẹ kí Ó dì mímọ fún wá pé láàrin ọdún mẹ́fà, Ilé Ìwòsàn ìkọní Fásiti wọ́n tí ṣe iṣẹ́ Àbẹ Ọkàn fún Ó kéré tán  ènìyàn mọkàndínlọgọ́tá lé lẹẹdẹgbẹ̀rún.  Méjìdínlógún lè ni Ẹ̀gbẹ́tá ìṣẹ Àbẹ tí wọn ṣé ní àṣeyọrí ni ó jẹ gbòógì.

 

“yàtọ sì bíbá àìní àwọn ènìyàn pàdé láwùjọ, àwọn Akẹkọọ wọ́n tún ní àǹfààní sì àwọn ìrìnṣé ̣àti ohùn èlò tí àwọn Akin Akẹkọọ ẹgbẹ wọ́n kó ní àǹfààní sí láti fi kẹkọọ tó ye kóòròkò.’’

 

Síwájú sí Ó ní eléyìí jẹ Ọ̀tá lé láàádọ̀tá Àjọ̀dún Olúdásílẹ́ tí  Àwọn Akẹkọọ Ilé Ẹkọ Òníwàsú tí Ile Ìjọ Adventist. Àti wí pé Ilé Ẹ̀kọ́ wọ́n jẹ Fásiti àdáni kejì ti wọ́n fún ní Àǹfààní àti ìwé ẹ̀rí láti kọ Ẹ̀kọ́ Okere, èyítí kó pọn dándàn láti kọ Ẹ̀kọ́ ní orígún mẹ́rin ògiri ilé ẹ̀kọ́ nìkan.

 

Olubunmi Adeyẹmọ.
Leave A Reply

Your email address will not be published.