Take a fresh look at your lifestyle.

Gómínà Seyi Makinde sékédùn pẹ̀lú gómìnà Ìpínlẹ̀ Òndó,Arákùnrin Akeredolu,

0 86

Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti ranṣẹ ẹku ara féra kù sí Gómìnà ìpínlẹ̀ Òndó, Arákùnrin Rotimi Akeredolu lórí ipapoda màmá rẹ to re ibi àgbà a re.

Gómìnà Makinde ẹni tí o ba Arákùnrin Akeredolu kẹ́dùn ipapoda màmá rẹ lásìkò tí o ṣe ibẹwo ẹku ara féra kù sí ilé oloogbe naa to wà ní agbègbè Orogun lo fi màmá wé ẹni rere nígbà ayé rẹ̀.

O wa so bákan náà pé, òun ba gbogbo èèyàn ìpínlè Òndó kedun fún ipapoda màmá Grace Akeredolu tó sì gba adura kí Olúwa tẹ màmá sí aféfé rere. O tun rọ Arákùnrin Akeredolu àti gbogbo mọlẹbi olóògbé láti ṣe ọkàn wọn gírí nítorí màmá gbé ìgbé ayé rere tó ṣe mú yangan.

 

Abiola Olowe
Ibàdàn

Leave A Reply

Your email address will not be published.