Take a fresh look at your lifestyle.

Àwòrán: Ìkẹ́nnẹ́ gbaradì Fún Rẹ́mọ Stars àti ASFAR

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 127

Ìkẹ́nnẹ́ ní ìpínlẹ̀ Ògùn kò ní gba ẹsẹ̀, Rẹ́mọ Stars yóò gbàlejò ẹgbẹ́ agbábọ́ọ́lù ASFAR torílẹ̀-èdè Mòrókò nínú ìdíje àkójọpọ̀ ife ẹ̀yẹ agbábọ́ọ́lù Adúláwọ̀ ,CAF  ní òpin ọ̀sẹ̀ yìí.

Remo Stars fakọyọ ni ọjọ Aiku nigbati o dọgba pẹlu awọn alatako rẹ ni ami ookan si ookan ni Rabat.

Ijade akọkọ ni fun awọn olowo miliọnu Ijẹbu, ṣugbọn ọgbọn ati iṣẹ akikanju  aṣojule Kayọde Bankọle, fun wọn ni  ami ookan si ookan laibikita bi awọn ọmo ilu naa ti lubẹ pa.

Bayi,asiko Remo Stars niyi lati fakọyọ.

Awọn ololufẹ wọn ti o ba fẹ  wo ere naa gbọdọ ra tikẹti wọn ni ibi ti ere naa yoo ti waye.

Nibayii, papa iṣere Ikenne ti di tuntun

Leave A Reply

Your email address will not be published.