Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Ṣáínà pè fún Ìṣọ̀kan Agbègbè, Lòdì sí “elẹ́yàmẹ̀yà àwọ̀”

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 59

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Sáínà, Xi Jinping ti rọ Rọ́síà àti àwọn ọmọ ẹgbẹ́ mìíràn ti àkójọ agbègbè kan láti ṣe àtìlẹyìn fún ara wọn fún ìdènà kí ipá àwọn àjèjì má baà ká wọn nítorí “ ìṣọ̀tẹ̀ àwọ̀” ní àwọn orílẹ̀-èdè wọn.

Xi ṣe ipe naa lati lodi si awọn rudurudu to lagbara kan ti o ti mì awọn orilẹ-ede Komunisiti tẹlẹ, lakoko ti o n sọrọ ni Usibekisitani nibi apejọ ẹgbẹ Iṣọkan  Shanghai (SCO) kan, akojọpọ eto aabo nipasẹ Saina ati Rọsia.

O sọ pe awọn orilẹ-ede ọmọ ẹgbẹ yẹ ki wọn ṣe atilẹyin awọn akitiyan ti ara wọn ti ṣe lati daabobo eto aabo ati awọn irè idagbasoke wọn.

Leave A Reply

Your email address will not be published.