Take a fresh look at your lifestyle.

2023: APC Kó ẹgbàájì-lé-ní-ọ̀kẹ́-mẹ̀ta dín – lókòó-lé-nígba Àwọn ọ̀dọ́ jọ Fún Ìṣẹ́gun Tinubu/Shettima

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 214

Ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressive Congress (APC) ní Anambara ní àwọn ti ṣe ìfilọ́lẹ̀ àwọn ọ̀dọ́ ẹgbàájì-lé-ní-ọ̀kẹ́-mẹ̀ta dín- lókòó-lé-nígba jákèjádò ìpínlẹ̀ náà láti ṣe àtìlẹ́yìn fún dídije ààrẹ rẹ̀, Sẹnetọ Bọ́lá Ahmed Tinubu, ní ìpínlẹ̀ náà.

Adari awọn ọdọ ẹgbẹ oṣelu nipinlẹ naa, Ejimofor Jideofor, lo sọ eyi lasiko ipade awọn ọdọ ti wọn ṣe fun ifilọlẹ ẹgbẹ ipolongo Tinubu/Shettima ni Awka, olu-ilu ipinlẹ naa.

O fi kun pe wọn ti pinnu lati ko awọn eniyan jọ fun lọpọlọpọ ti 0 si tun da loju pe oludije Aarẹ  ẹgbẹ ni o kere ju ida ogoji ninu ọgọrun  ibo ti wọn yoo di lakoko ibo ni ipinlẹ naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button