Take a fresh look at your lifestyle.

Sportify Tẹ Àtẹ̀jáde Ọ̀tun Orin Dáradára Fún Akọrin Burna Boy Pẹ̀lú Àkọ́lé ‘’ Last Last ’’

0 143

 

Orin náà ti àkólé rẹ̀ ń jẹ́ `ìgbẹ̀yìn Ìgbẹ̀yìn’  –  ‘’ Last Last ’’ lati ọwọ́ gbajúgbajà ònkọrin náà Damini, Ebunola Ogulu ti ìnangi rẹ̀ ńjẹ́ ` Burna Boy ‘ ti peregé ninu awo orin  ni ile Adulawo ti ẹnìkan soso da kọ ti Mílíọ̀nù ènìyàn n tele lori ero ayelukara Sportify.

 

Chart data lo kede re lori afefe ni kutukutu ojo kejila, osu kesan an odun 2022 lori ero twitter.

`Last Last’ je okan ti o se láàrín àsẹ̀sẹ̀ yọ àwo rẹ̀ to pe ni Ìfẹ́, Damini (Love Damini).

 

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave A Reply

Your email address will not be published.