Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-èdè Japan Ti Dáwọ́ Ìwádìí Nípa Ìwé Írínà Àwọn Arìnrìn Àjò Dúró

0 200

Ìjọba orílẹ̀-èdè Japan tí n pinu láti dáwọ́ Ìwádìí nípa Írínà làti àwọn orílẹ̀-èdè míràn dúró, èyi jẹ lára ìrọ̀rùn fún àìsàn COVID-19 tí wọn gbìyànjú láti dáwọ́ rè dúró ní enu bódà.

 

Olórí ìjọba Japan Fumio Kishida, lẹ ṣe ìpinnu náà kíákíá lati fún àwọn ènìyàn ní àfàní lati bẹ orílẹ̀-èdè Japan wo, láì sí gbígba ayé ká tó wolé

 

Oyébísí Adégbíté.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button