Ilé Ẹjọ Ìgbéjọ́ gbogbogbo tí orílẹ́-èdè Nàìjíríà tí sùn Ìgbéjọ́ àwọn olùkọ Fásítì sí ọjọ kẹrindilogun oṣù kẹsán ọdún yìí ní àkókò tí wọn yóò gbọ́ ẹdun ọkàn wọn lórí ìyànsẹ́lódí tó nlọ lọ́wọ́
Ni ọjọ́ ajé yìí ni agbẹjọ́rọ̀ fún ètò àwọn mèkúnú, Ebun-Olu Adegnoruwa, rọ ìjọba àpapọ̀ láti bọ̀wọ̀ fún àdéhùn ọdún 2009 lórí àwọn olùkọ Fásítì.
Ọjọ kẹrindilogun oṣù kẹsán ọdún yìí ni ilè ẹjọ mu láti gbọ ní enu ìjọba àpapọ̀ àti àwọn olùkọ Fásítì.
Oyébísí Adégbíté
Leave a Reply