Mínísítà orílẹ-èdè Nàìjíríà fún tí ìlú Abuja, Mallam Muhammed Musa Bello,ti sọ Akòwé tuntun fún ilẹ́ iṣẹ́ igbokègbodò ọkọ́ fún ìjọba, Abdullahi Adamu Candido àti amúgbá lẹ́gbẹ pàtàkì fún mínísítà to mójú tó àwọn òṣìṣẹ́, Farida Odangi Suleiman, láti rí wí pé wón ṣiṣẹ́ takuntakun fún àséyorí ìjọba Muhammed Buhari.
Mínísítà tẹ̀síwájú wípé ààrẹ Muhammed Buhari ni ìfẹ́ si ìlò síwájú àti àlàáfíà tí ìlú Abuja.
Ó fi iṣẹ́ yìn wọ́n, o sì sọ fún wọn láti tera mọ́ ṣe àti láti fi ọkàn jìn lati kojú àwọn ìṣòro tó n ṣe ìdíwọ́ fún, ìlú Abuja.
Àwọn olóyè tuntun naa ni wón gbà wọlé nípa ìjọba,èyí tí adájọ́ àgbà Kayode Adeniyi ṣe àkóso rè.
Oyèbísí Adégbìtẹ́.
Leave a Reply