Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-èdè Kánádà ṣe ayẹyẹ fún Ọba Charles

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 244

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Kánádà ti kéde Charles gẹ́gẹ́ bí ọba rẹ̀ pẹ̀lú ayẹyẹ ìfilọ́lẹ̀.

Ayẹyẹ naa waye ni ibugbe osise gomina gbogbogboo ni Ottawa, aṣoju ọba ni Ilu Kanada  ṣe ojuṣe olori ilu ni ipo Ọba.

Ìkéde

Olori ijọba, Justin Trudeau ati Gomina Gbogbogbo Mary Simon, fowo si aṣẹ  igbimọ ti n kede ọba-alade tuntun lẹyin ipade awọn alaṣẹ.

Ayẹyẹ naa pari pẹlu ibọn ikiini mọkanle-logun ati orin ẹgbẹ ologun “Ọlọrun yọ Ọba.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button