Take a fresh look at your lifestyle.

Kwara United yóò dojúko AS Douanes ní bòńkẹ́lẹ́

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 129

Àtúnṣe tuntun ti bá ìgbáradì fún ìdíje ìfesèwonsè CAF lápapọ̀ ti ife àpapọ̀ TotalEnergies CAF 2022/2023 láàrin ẹgbẹ́ agbábọ́ọ́lù Kwara United  àti AS Douanes, nítorí CAF ti pàse pé kí ìdíje náà wáyé ní bòńkélẹ́.

Idije na yoo waye ni gbagede Mobolaji Johnson loni (ọjọ Aiku,ọjọ kọkanla,  2022), ti yoo si bẹrẹ lati agogo mẹta ọsan.

Bi wọn ṣe n dide nibi Ipade Iṣaju idije naa ni ana, Kọmisọna Baramu, ajagun Tamba Langtombong lati Gambia sọ ipinnu CAF lori idije naa.

Ajagun Langtombong, ẹniti o ka ifiranṣẹ lati ọdọ CAF lori idije naa, ṣafikun pe wọn gbọdọ ṣe awọn eto  lati tẹle itọsọna tuntun naa.

Leave A Reply

Your email address will not be published.