Take a fresh look at your lifestyle.

FAO bẹnu àtẹ́ lu bí aginju ̀ṣe ń parun

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 155

Àjọ iṣọkan tó ń mójú tó ètò oúnjẹ àti iṣẹ́ àgbẹ̀ lagbaye (FAO), ti tako bí wọ́n ṣe n pàdánù aginjù látàrí pípa igbó run.

Gẹgẹ bi FAO ti ṣalaye, awọn aginju agbaye wa lọwọ ewu,nitori pe o ti le- nirinwo miliọnu eeka aginju to ti parun lati bii ọgbọn ọdun  sẹyin.

Leave A Reply

Your email address will not be published.