Take a fresh look at your lifestyle.

Olórí Eré Ọkọ̀ Wíwà Ayára Bíi Àsá tí a mọ̀ sí Formula 1 Sọpé Òndìje Lóbìnrin Kòleè Sí Ní Ọdún Màrún Sí Àkókò Yìí.

0 201

 

Ààrẹ eré ọkọ̀ wíwà ayára bí àsá ní ọ̀dàn, Stefano Domenicali ti sọpé òndìje lóbìnrin ní ipele àkọ́kọ́ kòleè seése kí ó wà ní ǹkan bíi ọdún màrún sí àkókò tí a wà yìí.
Ó fi kún pé áwọn sì ǹ sisẹ́ láti ri pé àwọn obìnrin tó pọ̀ náà yóò máa kópa. Àwon akíkanjú obìnrin méjì kópa ní ọdún 1950 ati 1970, Maria Teresa de Filippis àti , Lella Lombardi.

 

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button