Take a fresh look at your lifestyle.

Owó tó tó Bílíọ̀nù méjìdínlógún àti díẹ ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ná lórí epo rọ̀bì – Mínísítà

0 91

Mínísítà fún ètò nina owó lórílẹ̀dè Nàìjíríà, Zainab Ahmed, ló sọ wípé Bílíọ̀nù méjìdínlógún àti díẹ ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ná lórí ọ̀wọ́n gógó epo rọ̀bì lójojúmọ́

Mínísítà ló sọ èyí nígbà tí ó yọjú sí àwọn ìgbìmọ̀ abẹ́lé tí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin fà kalẹ̀ láti ṣe ìwádìí lórí epo rọ̀bì láti ọdún 2013 sí 2021.

Ọláyinká Akíntọ́lá.

Leave A Reply

Your email address will not be published.